ENGLISH LYRICS: To Thee, O Comforter divine
I will speak of the glorious honour of Thy majesty, and of Thy wondrous work. Ps. 145:51. To Thee, O Comforter divine
For all Thy grace and pow'r benign
Sing we Alleluia!
2. To Thee, whose faithful love had place
In God's great covenant of grace
Sing we Alleluia!
3. To Thee, whose faithful pow'r doth heal
Enlighten, sanctify and seal
Sing we Alleluia!
4. To Thee, our teacher and our friend
Our faithful leader to the end
Sing we Alleluia!
5. To Thee, by Jesus Christ sent down
Of all his gifts the sun and crown
Sing we Alleluia!
Amen
YORUBA LYRICS: Si O Olutunu Orun
Emi o Soro iyin olanla Re ti o logo, ati ti ise iyanu Re. OD. 145:5.1. Si O Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re,
A nko, Aleluya.
2. Si O, ife eni t’O wa
Ninu Majemu Olorun
A nko, Aleluya.
3. Si O, agbara Eni ti
O nwe ni mo, t’o nwo ni san
A nko, Aleluya.
4. Si O, Oluko at’ore.
Amona wa toto d’opin,
A nko, Aleluya.
5. Si O, Eniti Kristi ran,
Ade on gbogbo ebun Re,
A nko, Aleluya.
Amin.
0 Comments
Your comments are always appreciated!