ENGLISH LYRICS: Years I spent in vanity and pride
And when they were come to the place, which is called. Calvary.. Luke 23:331. Years I spent in vanity and pride,
Caring not my Lord was crucified,
Knowing not it was for me he died
On Calvary
Mercy there was great and grace was free
Pardon there was multiplied to me,
There my burden'd soul found liberty:
At Calvary.
2. By God's Word at last my sin I learned,
Then I trembl'd at the law I'd spurn'd
Till my guilty soul, imploring turned
To Calvary.
3. Now I've given to Jesus everything,
Now I gladly own Him as my King.
Now my raptured soul can only sing.
Of Calvary.
4. Oh! the love that drew salvation's plan
Oh! the grace that brought it down to man
Oh! the mighty gulf that God did span
At Calvary.
Amen.
YORUBA LYRICS: Mo lo odun pupo nin'ese
Nigbati nwon si de ibiti a npe Agbari, nibe ni nwon gbe kan a mo Agbelebu. Luk. 23:33
1. Mo lo odun pupo nin'ese
Lai bikita fun Oluwa mi
Lai mo pe 'tori mi lose ku
Ni Kalfari
Anu at'ore ofe Re po
O dariji mi lofe nibe
Nibe l'eru okan mi fo lo
Ni Kalfari
2. Oro Re fi ese mi mi han mi
Mo wariri niwaju ofin
Mo jebi, sugbon mo n'ireti
Ni Kalfari
3. Mo ti fi gbogbo re Jesu
Mo ti gba l'Oluwa at'Oba
Okan mi nyo mo si nko orin
Ti Kalfari
4. A! ife iyanu to gba ni
Or'ofe t'o wa mi lawari
Ogiri ikele ni ti wo
Ni Kalfari.
Amin.
Composed by William R. Newell.
0 Comments
Your comments are always appreciated!