ENGLISH LYRICS: He gave to me a seal
And when they had nothing to pay He frankly forgave them both. Luke 7:421. He gave to me a seal
Of the great debt I owe
And as He gave, He smiled and said,
"Always, remember Me"
2. He gave to me a seal
All of my debts He paid,
And as He gave, He smiled and said
"Always, remember Me."
3. I shall treasure the seal
Though, the debt is all paid
The seal told of the love of One
Who paid the debt for me.
4. I looked at it and smiled,
Again, I looked and wept
The earnest of His love for me,
I'll ever treasure it.
5. It is more than a seal
It is in remembrance,
That all the debt of sin was paid
By Lord, Emmanuel.
Amen.
YORUBA LYRICS: O fun mi l’edidi
Nigbati nwon ko si ni ti nwon o san, tinu-tinu li o dariji awon mejeji. Lk. 7:42.1. O fun mi l’edidi,
Gbese nla ti mo je
B’o ti fun mi, O si rerin
Pe; Mase gbagbe Mi.
2. O fun mi l’edidi
O san igbese na
B’o ti fun mi O si rerin
Wipe; ma ranti Mi!
3. Uno p’edidi na mo
B’igbese tile tan;
O nso ife Eni t’o san
Igbese na fun mi.
4. Mo wo mo si rerin
Mo tun wo mo sokun
Eri ife Re si mi ni
Uno toju re titi.
5. Ki tun s’edidi mo,
Sugbon iranti ni
Pe gbogbo igbese mi ni
Imanueli san.
Amin.
0 Comments
Your comments are always appreciated!