ENGLISH LYRICS: I've a message from the Lord
When he looketh upon it, shall live. Num.21;81. I've a message from the Lord,
Hallelujah!
The message unto you I'll give,
˜Tis recorded in His Word,
Hallelujah!
It is only that you "look and live"
Look and live," my brother, live!
Look to Jesus now and live,
Tis recorded in His Word,
Hallelujah!
It is only that you "look and live!"
2. I've a message full of love,
Hallelujah!
A message, O my friend, for you;
Tis a message from above,
Hallelujah!
Jesus said it, and I know 'tis true!
3. Life is offered unto thee,
Hallelujah!
Eternal life thy soul shall have,
If you'll only look to Him,
Hallelujah!
Look to Jesus who alone can save.
Amen
YORUBA LYRICS: Oluwa ran mi ni ‘se, Aleluya!
Nigbati o ba wo o, Yio ye. Num. 21:8.1. Oluwa ran mi ni ‘se, Aleluya!
Iwo ni uno je ise na fun;
A ko s’inu Oro Re, Aleluya!
P’eni t’o ba wo Jesu y’o ye.
Wo, k’o ye, Arakunrin,
Wo Jesu ki o si ye,
A ko s’inu Oro Re, Aleluya!
P’eni t’o ba wo Jesu y’o ye.
2. A ran mi n’ise ayo, Aleluya!
Uno j’isena fun o ore mi;
Ise lat’ oke wa ni; Aleluya!
Jesu SO, mo mo pe oto ni.
3. A n’owo iye si O, Aleluya!
A o fi ‘ye ailopin fun O;
T’o ba wo Jesu nikan, Aleluya!
Wo o, On nikan l’o le gbala. .
Amin
Composed by: William Augustine Ogden
0 Comments
Your comments are always appreciated!