ENGLISH LYRICS: Lord, Thy word abideth
Thy word is a lamp unto my feet. Ps.119:1051. Lord, Thy word abideth,
And, our footsteps guideth;
Who its truth believeth
Light and joy receiveth.
2. When our foes are near us,
Then Thy word doth cheer us,
Word of consolation
Message of salvation.
3. When the storms are o'er us,
And dark clouds before us,
Then its light directeth.
And our way protecteth.
4. Who can tell the pleasure,
Who recount the treasure,
By Thy word imparted
To the simple-hearted?
5. Word of mercy, giving
Succour to the living;
Word of life, supplying
Comfort to the dying!
6. O that we, discerning
Its most holy learning,
Lord, may love and fear Thee,
Evermore be near Thee!
Amen.
YORUBA LYRICS: Jesu oro Re ye
Oro Re ni fitila fun ese mi ati imolesi ipa ona mi. OD. 119:1051. Jesu oro Re ye,
O si nto ‘sise wa,
Eni t’o ba gba gbo,
Y’o l’ayo oun ‘mole.
2. Nigb’ ota sunmo wa,
Oro Re l’odi wa;
Oro itunu ni,
Iko igbala ni.
3. B’igbi at’okunkun
Tile bo wa mole;
‘Mole Re yo to wa,
Y’o si dabobo wa.
4. Tani le so ayo,
To le ka isura
Ti oro Re nfi fun
Okan onirele
5. Oro anu o nfi
‘Lera fun alaye;
Oro iye o nfi
Itunu feni nku.
6. Awa iba le mo
Eko ti O nkoni;
Ki a ba le fe O.
K’a si le sunmo O.
Amin.
0 Comments
Your comments are always appreciated!