ENGLISH LYRICS: We speak of the realms of the Blest
For He hath prepared for them a City. Heb. 11:161. We speak of the realms of the Blest,
Of that country so bright and so fair
And oft are its glories confess'd;
But what must it be to be to be there?
2. We speak of its pathways of gold,
Of its walls deek'd with Jewels most rare
Its wonders and pleasures untold
But what must it be to be there?
3. We speak of its freedom from sin,
From sorrow, temptation, and care,
From trials without and within?
But what must it be to be there?
4. We speak of its anthems of praise,
With which we can never compare,
The sweetest on earth we can raise;
But what must it be to be there?
5. We speak of its service of love,
Of the robes which the glorified wear,
The Church of the First-born above;
But what must it be to be there?
6. Do Thou, Lord, 'midst pleasure of woe,
Still for Heav'n our spirits prepare,
And shortly we also shall know
And feel what it is to be there.
Amen.
YORUBA LYRICS: A nsoro ile ‘bukun ni
…nitori ti o pese ilu kan sile fun won Heb. 11:16.1. A nsoro ile ‘bukun ni,
Ile didan at’ile ewa;
‘Gbagbogbo l’a nso t’ogo re
Y’o ti dun to lati de 'be!
2. A nsoro ita wura Re;
Oso odi re ti ko l’egbe
‘Faji re ko se f’enu so;
Y’o ti dun to lati de 'be!
3. A nso p’ese ko si nibe!
Ko s’aniyan at’ibanuje,
Pelu 'danwo l'ode, ninu;
Y’o ti dun to lati de ‘be!
4. A nsoro orin iyin re.
Ti a kole f’orin aye we,
B’o ti wu k'orin wa dun to
Y’o ti dun to lati de ‘be!
5. A nsoro isin ife re
Ti agbada t’awon mimo nwo,
Ijo akobi ti oke;
Y’o ti dun to lati de’be
6. Jo Oluwa t’ibi t’ire,
Sa se emi wa ye fun orun:
Laipe awa na yio mo
B’o ti dun to lati de ‘be.
Amin.
Composed by: Elizabeth K. Mills
0 Comments
Your comments are always appreciated!