ENGLISH LYRICS: O Lord of heav'n and earth and sea
For all things come of Thee, and of Thine own have we given Thee. 1 Chr. 29:141. O Lord of heav'n and earth and sea,
To Thee all praise and glory be;
How shall we show our love to Thee,
Giver of all!
2. The golden sunshine, vernal air,
Sweet flow'rs and fruits, Thy love declare
Where harvests ripen, Thou art there,
Giver of all!
3. For peaceful homes and healthful days,
For all the blessings earth displays,
We owe Thee thankfulness and praise,
Giver of all!
4. Thou didst not spare Thine only Son,
But gav'st Him for a world undone,
And freely with that Blessed One,
Thou givest all!
5. Thou giv'st the Holy Spirit's dow'r
Spirit of life, and love, and pow'r,
And dost His sev'nfold graces show'r
Upon us all.
6. For souls redeemed, for sins forgiv'n,
For means of grace, and hopes of Heav'n,
Father, what can to Thee be giv'n,
Who givest all?
7. We lose what on ourselves we spend:
We have as treasure without end
Whatever, Lord, to Thee we lend,
Who givest all!
8. Whatever, Lord, we lend to Thee
Repaid a thousandfold will be,
Then gladly will we give to Thee
Giver of all!
9. To Thee, from whom we all derive
Our life, our gifts, our pow'r to give
Oh, may we ever with Thee live.
Giver of all!
YORUBA LYRICS: Oluwa orun oun aye
Nitori ohun gbogbo odo Re ni o ti wa, ati ninu ohun owo Re li awa ti fi fun o. I Kro. 29:14.1. Oluwa orun oun aye,
‘Wo n’iyin at’ope ye fun fun:
Bawo la ba ti fe O to!
Onibu ore.
2. Orun ti nran, at’ afefe,
Gbogbo eweko nso ‘fe Re;
‘Wo l’O nmu irugbin dara,
Onibu ore.
3. Fun ara lile wa gbogbo,
Fun gbogbo ibukun aye
Awa yin O a si dupe;
Onibu ore.
4. O ko du wa li Omo Re,
O fi fun aye ese yi,
Pelu Re l’ofe l’o nfun wa
L’ohun gbogbo.
5. O fun wa l’Emi Mimo Re.
Emi iye at’ agbara,
O ro ‘jo ekun ‘bukun Re
Le wa l’ori.
6. Fun idariji ese wa,
Ati fun ireti orun,
Kil’ ohun t’a ba fifun O?
Onibu ore.
7. Owo ti a nna ofo ni,
Sugbọn eyi t’a fi fun O,
O je isura tit’ aye.
Onibu ore.
8. Ohun t’a bun O, Oluwa
‘Wo O san le pada fun wa,
L’ayo l’a o ta O lore
Onibu ore.
9. Ni odo Re l’a ti san wa,
Olorun Olodumare,
Je k’ale ba O gbe titi;
Onibu ore
Amin.
0 Comments
Your comments are always appreciated!